Òfin Kílowí

KÍLOWÍ Game Rules

Ifojusun wa ni lati ṣe awari, afihan ati lmugbooro ede Yoruba, lati fun awon oluta ayo ni iwuri lati lo awọn ọrọ ede Yoruba wọn pẹlu atinuda

The goal is to explore the Yoruba language, encouraging players to use their Yoruba vocabulary creatively

What is KÍLOWÍ?

KÍLOWÍ is a bilingual Yoruba-English card game that helps explore and learn the Yoruba language. The cards feature both Yoruba and English words, making it perfect for both Yoruba speakers and learners!

Game Rules

Click any card to flip between Yoruba and English

Rule 1 🚫📝 YOR

Iwọ kò gbọdọ̀ lo àwọn ọ̀rọ̀ mẹ́rin tí ó wà nínú ara káàdì náà.

Rule 1 🚫📝 ENG

You must not use the four words in the body of the card.

Rule 2 🗣️🇳🇬 YOR

Yorùbá nìkan ni Ọ gbọdọ̀ sọ, nígbàtí o ń gbìyànjú làti ṣàlàyé ọ̀rọ̀ tí ó wà ní òkè káàdì náà.

Rule 2 🗣️🇳🇬 ENG

You must speak only Yoruba while you are trying to explain the word at the top of the card.

Rule 3 💡🔊 YOR

Tí o bá ní ìdádúró, o lè lo àmì ohùn ọ̀rọ̀ náà.

Rule 3 💡🔊 ENG

If you're stuck, you may sound out the word.

Rule 4 🚫👋 YOR

Kò sí àáyè fún àwọn olùta ayò láti lo àfàrájúwe.

Rule 4 🚫👋 ENG

Players are not allowed to use gestures.

Special Rules

Rules for Yoruba Learners

Playing with Yoruba-Speaking Players

Perfect for mixed groups where some are learning Yoruba while others are fluent!

👤

The Learner's Role

Olùdíje tí kìí ṣe elédè Yorùbá mú káàdì náà, kò sì ṣe àpèjúwe ọ̀rọ̀ tí ó wà ní òkè káàdì náà ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.

The Yoruba-Learner holds the card and describes the word at the top of the card in English and/or Yoruba.

🗣️

The Speaker's Role

Olùdíje Ní Èdè Yorùbá gbọ́dọ̀ ṣe àmọ̀rò ọ̀rọ̀ náà, kí ó sì pèsè ìdáhùn ní èdè Yorùbá.

The Yoruba-speaking player (speaking only Yoruba) must guess the word and provide the answer in Yoruba.

💡

Need Help?

Tí o bá ní ìdádúró, o lè lo àmì ohùn ọ̀rọ̀ náà.

If you're stuck, you may sound out the word.

🚫

No Gestures

Kò sí àáyè fún àwọn olùta ayò láti lo àfàrájúwe.

Players are not allowed to use gestures.

Choose Your Game Mode

Select your group size to see customized gameplay instructions

Olùta Ayò Méjì / Two Players

1

Ó rọrùn fún eré ọkàn-sí-ọkàn láti ṣe ìdánwò fún ara wọn ní èdè Yorùbá.

Perfect for one-on-one play to test each other's proficiency in Yoruba.

2

Àwọn Olùta ayò yóo gbà fún ara wọn láti jẹ́ olùpè àti àmọ̀rò.

Players take turns being the caller and the guesser.

Àwọn Olùta Ayò mẹ́rin / Four Players

1

Ìbá fún àwọn ẹgbẹ́ kékeré, pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ méjì tí àwọn oṣeré méjì kọ̀ọ̀kan.

Great for small groups, with two teams of two players each.

2

Àwọn ẹgbẹ́ mìíràn yípadà bí olùpè àti àmọ̀rò.

Teams alternate turns as the caller and guesser.

Àwọn Ẹgbẹ́ Nlá / Larger Groups

1

Fún ìgbádùn diẹ̀ síi, ṣe àwọn ẹgbẹ́ mẹ́ta tàbí diẹ̀ síi.

For even more fun, form three or more teams.

2

Ẹgbẹ́ kọ̀ọ̀kan gbà àwọn eré eré, pẹ̀lú oṣeré kan bí olùpè àti ìyókù bí àwọn àmọ̀rò.

Each team takes turns playing, with one player as the caller and the rest as guessers.

Tips for Success

For Describers

  • Use synonyms and related concepts
  • Describe the function or use of the item
  • Give cultural context when helpful
  • Use gestures if allowed in your group

For Guessers

  • Think about word categories
  • Consider cultural references
  • Ask clarifying questions if allowed
  • Build on partial clues